Isikiẹli 17:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo igi inú igbó yóo mọ̀ péèmi, OLUWA, ni èmi í sọ igi ńlá di kékeré,mà sì máa sọ igi kékeré di ńlá.Mà máa sọ igi tútù di gbígbẹ,má sì máa mú kí igi gbígbẹ pada rúwé.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni n óo sì ṣe.”

Isikiẹli 17

Isikiẹli 17:18-24