Isikiẹli 17:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lórí òkè gíga Israẹli ni n óo gbìn ín sí,kí ó lè yọ ẹ̀ka, kí ó so,kí ó sì di igi Kedari ńlá.Oríṣìíríṣìí ẹranko ìgbẹ́ ni yóo máa gbé abẹ́ rẹ̀.Oríṣìíríṣìí ẹyẹ yóo pa ìtẹ́ sí abẹ́ òjìji ẹ̀ka rẹ̀.

Isikiẹli 17

Isikiẹli 17:20-24