Isikiẹli 16:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ, n óo ranti majẹmu tí mo bá ọ dá ní ìgbà èwe rẹ. N óo sì bá ọ dá majẹmu tí kò ní yẹ̀ títí lae.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:57-63