Isikiẹli 16:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìṣe àní, àní, OLUWA Ọlọrun ní, “N óo ṣe sí ọ, bí ìwà rẹ. O kò ka ìbúra mi sí, o sì ti yẹ majẹmu mi.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:52-63