Isikiẹli 16:31 BIBELI MIMỌ (BM)

O mọ ilé oriṣa sí òpin gbogbo òpópó, o sì ń kọ́ ibi ìrúbọ sí gbogbo gbàgede. Sibẹ o kò ṣe bí àwọn alágbèrè, nítorí pé o kò gba owó.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:30-39