Isikiẹli 16:30 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní ọkàn rẹ ti kún fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ jù! Ó ń wò ọ́ bí o tí ń ṣe gbogbo nǹkan wọnyi bí alágbèrè tí kò nítìjú!

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:28-40