Isikiẹli 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

O tún ṣe àgbèrè ẹ̀sìn pẹlu àwọn ará Ijipti, àwọn aládùúgbò rẹ, oníṣekúṣe. Ò ń mú kí ìwà àgbèrè rẹ pọ̀ sí i láti mú mi bínú.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:18-33