Isikiẹli 16:25 BIBELI MIMỌ (BM)

O mọ ìtẹ́ gíga ní òpin gbogbo òpópó. O sì ń ba ẹwà rẹ jẹ́ níbẹ̀, ò ń ta ara rẹ fún gbogbo ọkunrin tí wọn ń kọjá, o sì sọ àgbèrè rẹ di pupọ.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:20-33