Isikiẹli 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

O mú aṣọ rẹ tí a ṣe ọnà sí lára, o dà á bò wọ́n. O gbé òróró ati turari mi kalẹ̀ níwájú wọn.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:16-19