Isikiẹli 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

O mú ninu àwọn ohun ọ̀ṣọ́ wúrà ati ti fadaka rẹ, tí mo fún ọ, o fi wọ́n ṣe ère ọkunrin, o sì ń bá wọn ṣe àgbèrè.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:12-24