Isikiẹli 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn o gbójú lé ẹwà rẹ; o di alágbèrè ẹ̀sìn nítorí òkìkí rẹ, o sì ń bá gbogbo àwọn eniyan tí wọn ń kọjá ṣe àgbèrè.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:8-23