Isikiẹli 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkìkí ẹwà rẹ wá kàn ká gbogbo orílẹ̀-èdè; o dára nítorí pé èmi ni mo fún ọ ní ẹwà. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:8-16