Isikiẹli 16:1-3 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, fi nǹkan ìríra tí Jerusalẹmu ń ṣe hàn án,