Isikiẹli 16:3 BIBELI MIMỌ (BM)

kí o sì sọ fún un pé, OLUWA Ọlọrun sọ nípa Jerusalẹmu pé:“Ilẹ̀ Kenaani ni a bí ọ sí; ibẹ̀ ni orísun rẹ. Ará Amori ni baba rẹ ará Hiti sì ni ìyá rẹ.

Isikiẹli 16

Isikiẹli 16:1-12