Isikiẹli 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku kọjú sí ìhà mẹrin, ó sì lè lọ tààrà sí ìhà ibi tí ẹ̀mí rẹ̀ bá darí sí láì ṣẹ̀ṣẹ̀ yí ojú pada kí ó tó máa lọ.

Isikiẹli 1

Isikiẹli 1:9-18