Isikiẹli 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n na ìyẹ́ wọn sókè, ọ̀kọ̀ọ̀kan na ìyẹ́ meji meji kan ìyẹ́ ẹni tí ó kángun sí i, wọ́n sì fi ìyẹ́ meji meji bora.

Isikiẹli 1

Isikiẹli 1:6-17