Ìfihàn 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eṣú ti tú jáde láti inú èéfín náà, wọ́n lọ sí orí ilẹ̀ ayé. A fún wọn ní agbára bíi ti àkeekèé ayé.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:1-13