Ìfihàn 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣí kànga náà, èéfín bá yọ láti inú kànga yìí, ó dàbí èéfín iná ìléru ńlá. Oòrùn ati ojú ọ̀run bá ṣókùnkùn nítorí èéfín tí ó jáde láti inú kànga náà.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:1-12