Ìfihàn 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ ìràwọ̀ náà ni “Igi-kíkorò.” Ó mú kí ìdámẹ́ta omi korò, ọ̀pọ̀ eniyan ni ó sì kú nítorí oró tí ó wà ninu omi.

Ìfihàn 8

Ìfihàn 8:4-13