Ìfihàn 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli kẹta fun kàkàkí rẹ̀. Ìràwọ̀ ńlá kan bá já bọ́ láti ọ̀run. Ó bẹ̀rẹ̀ sí jóná bí ògùṣọ̀. Ó bá já sinu ìdámẹ́ta àwọn odò ati ìsun omi.

Ìfihàn 8

Ìfihàn 8:3-11