Ìfihàn 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbọ́ iye àwọn tí a fi èdìdì sí níwájú, wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ meje eniyan ó lé ẹgbaaji (144,000) láti inú gbogbo ẹ̀yà ọmọ Israẹli:

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:2-9