Ìfihàn 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ má ì tíì ṣe ilẹ̀ ayé ati òkun ati àwọn igi ní jamba títí tí a óo fi fi èdìdì sí àwọn iranṣẹ Ọlọrun wa níwájú.”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:1-5-8