Ìfihàn 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun yìí bi mí pé, “Ta ni àwọn wọnyi tí a wọ̀ ní aṣọ funfun? Níbo ni wọ́n sì ti wá?”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:12-17