Ìfihàn 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń wí pé, “Amin! Ìyìn, ògo, ọgbọ́n, ọpẹ́, ọlá, agbára ati ipá ni fún Ọlọrun wa lae ati laelae. Amin!”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:10-16