Ìfihàn 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí mú kí ó di dandan fún àwọn eniyan Ọlọrun, tí wọn ń pa àṣẹ Ọlọrun mọ́, tí wọ́n sì dúró ninu igbagbọ Jesu láti ní ìfaradà.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:6-18