Ìfihàn 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Èéfín iná oró àwọn tí wọ́n bá júbà ẹranko náà ati ère rẹ̀, tí wọ́n gba àmì orúkọ rẹ̀, yóo máa rú títí lae. Kò ní rọlẹ̀ tọ̀sán-tòru.”

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:10-20