Ìfihàn 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

A fún un ní ẹnu láti fi sọ̀rọ̀ tí ó ju ẹnu rẹ̀ lọ, ọ̀rọ̀ àfojúdi sí Ọlọrun. A fún un ní àṣẹ fún oṣù mejilelogoji.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:4-14