Ìfihàn 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń júbà Ẹranko Ewèlè náà nítorí pé ó fi àṣẹ fún ẹranko yìí. Wọ́n sì ń júbà ẹranko náà, wọ́n ń sọ pé, “Ta ni ó dàbí ẹranko yìí? Ta ni ó tó bá a jà?”

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:1-9