Ìfihàn 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún àwọn ẹlẹ́rìí mi meji láṣẹ láti kéde iṣẹ́ mi fún ọtalelẹgbẹfa (1260) ọjọ́. Aṣọ ọ̀fọ̀ ni wọn yóo wọ̀ ní gbogbo àkókò náà.”

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:1-5