Ìfihàn 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Má wulẹ̀ wọn àgbàlá Tẹmpili tí ó wà lóde, nítorí a ti fi fún àwọn alaigbagbọ. Wọn yóo gba ìlú mímọ́ fún oṣù mejilelogoji.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:1-9