Ìfihàn 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà kọ àwọn ohun tí o rí sílẹ̀, ati àwọn ohun tí ó wà nisinsinyii ati àwọn ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:18-20