Ìfihàn 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni ẹni tí ó wà láàyè. Mo kú, ṣugbọn mo ti jí, mo sì wà láàyè lae ati laelae. Àwọn kọ́kọ́rọ́ ikú ati ti ipò òkú wà lọ́wọ́ mi.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:11-20