Ìṣe Àwọn Aposteli 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bèèrè pé, “Ta ni ọ́, Oluwa?”Ẹni náà bá dáhùn pé, “Èmi ni Jesu, ẹni tí ò ń ṣe inúnibíni sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:1-10