Ìṣe Àwọn Aposteli 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

ó bá ṣubú lulẹ̀. Ó wá gbọ́ ohùn ẹnìkan tí ó bi í pé, “Saulu! Saulu! Kí ló dé tí o fi ń ṣe inúnibíni sí mi?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:1-10