Ìṣe Àwọn Aposteli 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa bá sọ fún un pé, “Dìde. Lọ sí títì tí à ń pè ní ‘Títì títọ́,’ ní ilé Judasi kí o bèèrè ẹni tí ó ń jẹ́ Saulu, ará Tasu. O óo bá a ní ibi tí ó gbé ń gbadura.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:4-20