Ìṣe Àwọn Aposteli 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ-ẹ̀yìn Jesu kan wà ní Damasku tí ń jẹ́ Anania. Oluwa pè é ní ojú ìran, ó ní, “Anania!”Anania bá dáhùn pé, “Èmi nìyí, Oluwa.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:6-15