Ìṣe Àwọn Aposteli 8:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọn tí ń lọ lọ́nà, wọ́n dé odò kan. Ìwẹ̀fà náà sọ pé, “Wo omi. Kí ló dé tí o ò fi kúkú rì mí bọmi?” [

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:30-37