Ìṣe Àwọn Aposteli 8:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Filipi bá tẹnu bọ ọ̀rọ̀. Ó bẹ̀rẹ̀ láti ibi àkọsílẹ̀ yìí, ó waasu ìyìn rere Jesu fún un.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:27-37