Ìṣe Àwọn Aposteli 8:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Saulu bá wọn lọ́wọ́ sí ikú rẹ̀.Láti ọjọ́ náà ni inúnibíni ńlá ti bẹ̀rẹ̀ sí ìjọ tí ó wà ní Jerusalẹmu. Gbogbo àwọn onigbagbọ bá túká lọ sí gbogbo agbègbè Judia ati Samaria. Àwọn aposteli nìkan ni kò kúrò ní ìlú.

2. Àwọn olùfọkànsìn sin òkú Stefanu, wọ́n sì ṣọ̀fọ̀ pupọ lórí rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8