Ìṣe Àwọn Aposteli 7:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ó bá kúnlẹ̀, ó kígbe, ó ní, “Oluwa, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn lọ́rùn.” Nígbà tí ó sọ báyìí tán, ó kú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:50-60