Ìṣe Àwọn Aposteli 7:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń sọ òkúta lu Stefanu, ó ké pe Jesu Oluwa, ó ní, “Oluwa Jesu, gba ẹ̀mí mi.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:58-60