Ìṣe Àwọn Aposteli 7:39 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn àwọn baba wa kò fẹ́ gba ọ̀rọ̀ rẹ̀ gbọ́. Wọ́n tì í kúrò lọ́dọ̀ wọn; ọkàn wọn tún pada sí Ijipti.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:32-41