Ìṣe Àwọn Aposteli 7:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose náà ni ó bá angẹli sọ̀rọ̀ ní òkè Sinai nígbà tí wọ́n wà ninu àwùjọ ní aṣálẹ̀, tí ó tún bá àwọn baba wa sọ̀rọ̀. Òun ni ó gba ọ̀rọ̀ ìyè láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun tí ó fi fún wa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:36-45