Ìṣe Àwọn Aposteli 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, ó yọ sí àwọn kan tí wọn ń jà. Ó bá ní kí òun parí ìjà fún wọn. Ó ní, ‘Ẹ̀yin ará, arakunrin ara yín ni ẹ̀ ń ṣe. Kí ló dé tí ẹ̀ ń lu ara yín?’

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:23-30