Ìṣe Àwọn Aposteli 7:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rò pé yóo yé àwọn arakunrin òun pé Ọlọrun yóo ti ọwọ́ òun fún wọn ní òmìnira. Ṣugbọn kò yé wọn bẹ́ẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:19-26