Ìṣe Àwọn Aposteli 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ̀yin ará, ẹ wá ẹni meje láàrin yín, tí wọ́n ní orúkọ rere, tí wọ́n kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ ati ọgbọ́n, kí á yàn wọ́n láti mójútó ètò yìí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:1-11