Ìṣe Àwọn Aposteli 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn aposteli mejila bá pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu yòókù jọ, wọ́n ní, “Kò yẹ kí á fi iṣẹ́ iwaasu ọ̀rọ̀ Ọlọrun sílẹ̀, kí á máa ṣe ètò oúnjẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:1-5