Ìṣe Àwọn Aposteli 5:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Lojoojumọ, ninu Tẹmpili ati láti ilé dé ilé, wọn kò dẹ́kun láti máa kọ́ eniyan ati láti máa waasu pé Jesu ni Mesaya.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:40-42