Ìṣe Àwọn Aposteli 5:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n jáde kúrò níwájú ìgbìmọ̀, wọ́n ń yọ̀ nítorí a kà wọ́n yẹ kún àwọn tí a fi àbùkù kan nítorí orúkọ Jesu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:36-42