Ìṣe Àwọn Aposteli 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹnìkan bá dé, wọ́n sọ fún wọn pé, “Àwọn ọkunrin tí ẹ tì mọ́lé wà ninu Tẹmpili, tí wọn ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:20-27